Album Cover Méjì Méjì

Méjì Méjì

Brymo

6

Mò fí iyẹ′ mi fo

Mò ri'rè

Mò wò waju, mò w′okéÌrè dé

Kí ìjò mọlẹ, mo tún takasúfè

O dún mọ mí òó

O dún mọ mí òó

O dún mọ mí òó òó

O dún mọ' mí òó

Méjì-méjì làá d'àiyé ò

(Méjì-méjì làá d′àiyé ò)

Ìfẹ rẹ sí mí, o jìn gángan

(Méjì-méjì làá d′àiyé ò)

Méjì-méjì làá d'àiyé ò

(Méjì-méjì làá d′àiyé ò)

Ìfẹ rẹ sí mí, ò jìn gángan

(Méjì-méjì làá d'àiyé ò)

Ọrẹ, dákun rò kò tó lọ

Mò tàràkà, mo ṣubu

Kín tó kọ òun món sọ

Yàrá gbọrọ, lọrá fèsì

Ẹsìn o gbani

Ìwà o lani

Òún tó wùn ′nì ló nwa ní

Ọrẹ, dákun rò kò tó lọ

Mo tàràkà, mo ṣubu

Kín tó mọ òun món sọ

Yàrá gbọrọ, lọrá fèsì

Ẹsìn o gbani

Ìwà o lani

Òún tó wùn'nì ló nwa ni

Mó fi iyẹ mí fo

Mo rí′rè

Mó wò 'wájú, mo w'òkè

Ìrè dé

Kí ijó mọlẹ, mo tún takasúfè

O dùn mọ mí óò

O dùn mọ mí óò

O dùn mọ mí óò

O dùn mọ mí óò

Méjì-méjì làá d′àiyé óò

(Méjì-méjì làá d′àiyé óò)

Ìfẹ rẹ sí mí, o jin gángan

(Méjì-méjì làá d'àiyé óò)

Méjì-méjì làá d′àiyé óò

(Méjì-méjì làá d'àiyé óò)

Ìfẹ rẹ sí mí, o jin gángan

(Méjì-méjì làá d′àiyé óò)

Méjì-méjì làá d'àiyé óò

(Méjì-méjì làá d′àiyé óò)

Ìfẹ rẹ sí mí o jin gángan

(Méjì-méjì làá d'àiyé óò)

Méjì-méjì làá d'àiyé óò

(Méjì-méjì làá d′àiyé óò)

Ìfẹ rẹ sí mí o jin gángan

(Méjì méjì làá d′àiyé óọ')