Album Cover Àkọ́kọ́

Àkọ́kọ́

Brymo

7

Emi ni, emi l′eni na

Okunrin meta ati abo tan fi orin ko

Emi ni, emi l'omo naOkunrin merin ati abo, won t′enu mo

Mo la'nu, mo soro

Mo yo ake, mo foh oro

Omo olooforo

Mo je akara oforo

Emi ni ah, emi ni oh

Emi ma l'eni tan soh nigboro

Emi ni yaa, emi ni yoo

Awon mama gan n′ soro ni popo

Won lemi l′àkókó

Won lemi l'àkókó óh-oh

Won lemi l′àkókó óh-oh

Won lemi l'àkókó óh-oh

Emi ni okunrin na

T′awon majesin nso pe m'orin gan

Emi ni, emi l′omo na

Gbogbo ara adugbo lon t'enu mo

Emi baba olowo

Mo sh'owo, mo j′ere

Iwa ati opolo lon lo

Awon ota ti ru po

Emi ni ah, emi ni ah

Emi ma l′eni ton soh nigboro

Emi ni yaa, emi ni yoo

Awon omoge n' re′di ni popo

Won l'emi l′àkókó

(Iwo l'àkókó)

Won lemi l′àkókó oh-oh

(Iwo l'àkókó oh-oh)

Won lemi l'àkókó oh-oh

(Iwo l′àkókó oh-oh)

Won lemi l′àkókó oh-oh

(Iwo l'àkókó oh-oh)

Won l′emi l'àkókó

(Iwo l′àkókó)

Won lemi l'àkókó oh-oh

(Iwo l′àkókó oh-oh)

Won lemi l'àkókó oh-oh

(Iwo l'àkókó oh-oh)

Won lemi l′àkókó oh-oh

(Iwo l′àkókó oh-oh)