Album Cover Ọlánrewájú

Ọlánrewájú

Brymo

7

Igba o lọ bi orere

Bo ba koro, oṣi maa dun ah

Eni to ni suuru, kii ṣeyan kekereBo ba kan lẹ, oṣi maa goke ah

Boo ba ṣe un tọ fe, won maa kẹyin si e (ẹh a ẹh)

Bo ba ṣe tirẹ o, o ma jẹ ire fun ẹ (ẹh a ẹh)

Ọlanrewaju ọmọ ọba

E ma suure da gba, won ni ko o ṣe were, roora ṣe

E ma suure da gba oo

Olooto ko ni ku si bi ọtẹ ooo

Olanrewaju ọmọ mi, e ma suure da gba oo

Igba o lọ bi orere

Bọmọde oku oo, oṣi maa da gba

Ṣọra funja, ṣọ ra fẹgbẹkẹgbẹ

Oun tio to o, oṣi maa pọ da nu

Gbogbo eni abi lo ma ku, eh

Eh a ẹh

Iwa ta a wu lo ma ku (ẹh a ẹh)

Ọlanrewaju ọmọ oba, e ma suure da gba o

Won ni ko ṣe were, roora ṣe

E ma suure da gba oo

Olooto ko ni ku sibi ọtẹ oo

Ọlanrewaju ọmọ mi, e ma suure da gba o

Olooto ko ni ku sipo ika oo

Olooto ko ni ku sibi ote oo

Ọlanrewaju ọmọ ọba, ee ma suure dagba oo

Ọlanrewaju ọmọ mi, ee ma suure da gba oo