Barry Jhay
1 ContributorSee Me See god (SMSG) Lyrics
[Intro: Chief Dr. Sikiru Ayinde Barrister (MFR) & Barry Jhay]
Ẹ maa ka mi mọ wọn, ṣe ni mo da duro
Ọrọ mi d'akọ alangba, ko ṣe jẹ ni tutu
Koda, ko ṣe China t'ọn gbe ti n jẹ wọn
Ẹni j'alangba n tutu, a kó warapa
Oh-ah, oh-ah-ah-ah
Yeah, ay-ya-ay, ah-ah, ah
Oh-wa, oh, wa-wa-wa
(Nobody's perfect)
[Verse 1]
Yea, ki'ku ma-ma pa awọn to gbe mi s'ori bi gele
Ki ibanujẹ jina siwa rere, tefe-tefe
K'iku ma p'ọta mi, ko le r'iran wo
(O ri mo fa to n jo, and they no fit hold me, different effect, ah)
Ki'ku ma p'ọta mi, ko le r'iran wo
(Mo ṣi n m'ẹyẹ bọ lapo, jẹ gbese Lapo, ọta mi lo n jẹ gbese, mo mọwọ na)
[Pre-Chorus]
If I see say wahala don dey too much, na to roll up a big fat one
Motivation gan ti n pa'yan, wahala nikan kọ o
Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ (Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ)
[Chorus]
See me, see God o, abi emi naa kọ
Ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah-yeah
Ṣe you dey see level o?
Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yеah, tẹti mọ ọ, ye
[Verse 2]
Ye, as I dey find wеtin I go chop, ooh-iy
Make I no jam wetin go chop me
Olúwa lo gbe (Yea-yea), lo gbe mi s'oke
Emi ko le ṣ'ai ṣope
[Chorus]
See me, see God o, abi emi naa kọ
Ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah-yeah
Ṣe you dey see level o? (Ṣe you dey see level o?)
Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, tẹti mọ ọ (Yeah)
Yeah, o l'oju ọmọ to damọ
[Pre-Chorus]
If I see say wahala don dey too much, na to roll up a big fat one
Motivation gan ti n pa'yan, wahala nikan kọ o
Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ (Ika ọwọ ko ni aṣọ, ori ṣa lo n ko mi yọ)
[Chorus]
See me, see God o, abi emi naa kọ
Ọmọde ana ti wèrè bọ, gentle boy, yeah-yeah
Ṣe you dey see level o? (Ṣe you dey see level o?)
Barry lo n bọ, ọmọ ọba lo n bọ, oh yeah, tẹti mọ ọ (Yeah)
Yeah, o l'oju ọmọ to damọ
[Outro]
Sunshine