Album Cover Sabi

Sabi

MohBad

6

(No one is sleeker)

Wọn ní kíń wá bàbá tó sabiK′owá w'orí mi, k′òtò saasi

Kíń má ṣe ya'wó l'ọ′wọ′ Lati

Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ kó dàbí oh

Wọn ní kíń wá bàbá tó sabi oh (ehn-ehn, ehn)

K′owá w'orí mí, k′òtò saasi (uhn-uhn, uhn)

Kíń má ṣe ya'wó l′ọ'wọ' Lati

Mo m′orin kọ, wọn fẹ jẹ kó dàbí o

Uh, ọmọ ológo tó sabi

Ọmọ gbéra tán, ò b′omi sí garri

Ó wọ Yankee o, Atlanta per roof

Èèyàn Baba Fela ní, kẹ gbà fún

Uh, ọmọ ológo tó sabi

Ọmọ gbéra tán o, ò b'omi sí garri

Ó wọ Yankee o, Atlanta per roof

Èèyàn Baba Fela ní, kẹ gbà fún

Huh, kí lódé o jere o?

Mo má j′àyé mí kọto fun fèrè oh

Uh, oṣe o, oṣe, oṣe o jere oh

Tińbá ṣíṣẹ́, kíń má ko'rè oko dé′lé oh

Wọn gùn'yàn mí kéré o

Mo fíìmù wọn fon fèrè oh

Nínú àyé, mí o kéré o

T′obà dé ìgbòrò, k'olo béèrè oh

Wọn ní kíń wá bàbá tó sabi

K'owá w′orí mi, k′òtò saasi

Kíń má ṣe ya'wó l′ọ'wọ′ Lati

Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ kó dàbí oh

Wọn ní kíń wá bàbá tó sabi oh (ehn-ehn, ehn)

K′owá w'orí mí, k'òtò saasi (uhn-uhn, uhn)

Kíń má ṣe ya′wó l′ọ'wọ′ Lati

Mo m'orin kọ, wọn fẹ jẹ kó dàbí o

Uh, ọmọ ológo tó sabi

Ọmọ gbéra tán o, ò b′omi sí garri

Ó wọ Yankee o, Atlanta per roof

Èèyàn Baba Fela ní, kẹ gbà fún

Huh, ọmọ ológo tó sabi

Ọmọ gbéra tán o, ò b'omi sí garri

Ó wọ Yankee o, Atlanta per roof

Èèyàn Baba Fela ní, kẹ gbà fún

Huh, kí lódé o jere o?

Mo má j′àyé mí kọto fun fèrè oh

Uh, oṣe o, oṣe, oṣe o jere o

Tińbá ṣíṣẹ́, kíń má ko'rè oko dé'lé oh

Uh, wọn gùn′yàn mí kéré oh

Mo fíìmù wọn fon fèrè oh

Nínú àyé, mí o kéré

T′obà dé ìgbòrò, k'olo béèrè oh

I will exalt You, Lord

For You have lifted me out

Has not let my foes to rejoice over me

(Timi Jay on the track)